Òkú Họnọrebu Jagaban wọ káà ilẹ̀ sùn

Wọ́n ti sin òkú Họnọrébù tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò Àríwá Ìbàdàn nílé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin l’Àbújá, Ọlájídé Akínrẹ̀mí tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí “Jagaban” ní ilé rẹ̀ tó wà ní Temidire Estate ní agbègbè Ológúnẹrú nílùú Ìbàdàn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbí, ará,…